Special Invitation To All Mothers And Mothers To Be. (Virtuous Mothers' Summit 2019)
IPAGO AWON OBINRIN TI O LOGO NI ODUN 2019
ABIYAMO TOOTO
OO!
AKOKO TO LATI GBA ADURA WAKATI META, LAI DA ENU DURO LORI AWON OMO Ti OLUWA FUN WA
O.TO GE!
ISE ESU LORI OMO
ABIYAMO GBUDO JE OHUNJE OMO NINU IRORUN
OPIN DE BA AINI
ATI IPOJU NINU AYE AWON OMO WA
NITORI IDI EYI
DARAPO MO
AWON ABIYAMO TOOTO
TO FE ILOSIWAJU
ATI AYO LORI OMO WON.
ADURA WAKATI META YII
YOO WAYE NI
OJO ISINMI KEJI NI OSU KEJI, ODUN 2019
(10 / 2 / 2019)
Venue: Aare BAMOFIN AFE BABALOLA
AB FOUNDATION CIVIC CENTRE, ABA-EBIRA, NI IDOJUKO OPOPO ADEBAYO ADO EKITI, EKITI STATE.
Time: 2:00pm -5:00pm
Theme:. "MY SEED DIVINELY BLESSED"
JOWO WA SI IBI IPADE ADURA YII PELU IGBAGBO RE
IWO YOO RI OWO IYANU OLORUN LORI GBOGBO AWON OMO RE
WA PELU TWO SET OF IPELE RE
LATI GBADURA FUN ORISUN AWON OMO TOLUWA FI FUN E
WA PELU IGO ORORO (ONE GOYA OIL)
OLUPE IPADE:
LOLA ADEGBOLA
ASOJU OLORUN FUN:
VIRTUOUS WOMEN PRAYER MINISTRY EKITI STATE, NIGERIA
KINDLY PRAY, PLAN AND PREPARE TO ATTEND THIS SPECIAL PROGRAM
AND INVITE FRIENDS,
MOTHERS
AND MOTHERS TO BE.
WE SHALL NOT LABOUR IN VAIN IN JESUS NAME AMEN
KINDLY BELOVED,
FORWARD THIS SPECIAL INVITATION TO ALL GLORIOUS MOTHERS AND MOTHERS TO BE IN YOUR CONTACT.
JESUS IS THE LORD
Comments
Post a Comment