Kòrónáfairọ̀ọ̀sì kò dí ètò ìdìbó ìpínlẹ Edo, Òǹdó lọ́wọ́--INEC

Fẹ́mi Akínṣọlá

Ó dà bí ẹni pé ń tí ń ṣe Lébáńdé kò s'ọmọ rẹ o, Lébáńdé ń sunkún ọmú, ìyá rẹ  ń sunkún ebi, ló díá fún bí àjọ elétò ìdìbò  Nàìjíríà ti kéde pé àjàkálẹ̀ àrùn apinni léèmí coronavirus kò dí àwọn lọ́wọ́ rárá láti múra sílẹ̀ de àṣeyọrí ètò ìdìbò ní ìpínlẹ̀ Òǹdó àti Ẹdó.

Wọ́n ní kò sí ayípadà kankan lórí àwọn ìgbésẹ̀ tó yẹ ní gbígbé láti ṣètò ìdìbò gómìnà àti àwọn ọmọ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ní àwọn ìpínlẹ̀ méjéèjì náà..

Ìpínlẹ̀ Edó wà ní Gúúsù Gúúsù Nàìjíríà nígbà tí ìpínlẹ̀ Òǹdó wà ní ìwọ̀ oòrùn Gúúsù Orílẹ̀ yìí.

Comments

Popular posts from this blog

Murder Case: Ekiti APC Boss, Two Others Discharged, Acquitted