Posts

Ọ̀daràn kan fi tipá wọ ààfin Ọ̀ọni ilé ifẹ̀

Image
Fẹ́mi Akínṣọlá A kìí gbélé ẹni ká fi ọrùn rọ́ ni a ti ń gbọ́ tipẹ́ tipẹ́, sùgbọ́n kín wá ni ká ti pe tirúfẹ́ ìṣẹ̀lẹ̀ ajániláyà yìí tó wáyé ní ààfin Ọọ̀nirìṣà Ọba Adéyẹyè Ògúnwùsì,ní alẹ́ ọjọ́ Ìṣẹ́gun níbi tí àwọn èèyàn ìlú Ilé Ifẹ̀ ni àwọn ti ń gbọ́ ìró ìbọn ní kíkàn kíkan ní ilé Oòduà tíí ṣe ààfin Ọọ̀nirìṣà Ilé Ifẹ̀, Ọba Adéyẹyè Ògúnwùsì . Eléyìí ló ṣì mú kí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn èèyàn ìlú  ìṣèǹbáyé náà ó máa kó àyà sókè lórí àlàáfíà Ọọ̀nirìṣà Adéyẹyè Ògúnwùsì. Nígbà tí gbogbo rẹ̀ yóó fi rọlẹ̀ ni ìròyìn jáde pé àwọn èèyàn mẹ́ta kan gbìyànjú láti fi ipá wọ ààfin nínú ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ kan. Nígbà tí wọ́n dé ìloro àkọ́kọ́ ní ààfin Ọọ̀nirìṣà ní àwọn ẹ̀ṣọ́ bèèrè ohun tí wọ́n wá ṣe, tí méjì nínú wọn sì bẹ́ sílẹ̀ nínú mọ́tò tí wọ́n sì fi ẹsẹ̀ fẹ́ ẹ. Ẹnì kẹta wọn tó wa ọkọ̀ náà ni wọ́n ní ó fi ọkọ̀ náà já ìloro kínní àti ìkejì pẹ̀lú èròńgbà láti wọ ìloro kẹta níbi tí Kábíyèysí àrólé Oòduà, Ọọ̀nirìṣà Ọba Ògúnwùsì ń gbé, ṣùgbọ́n àwọn agbófinró tó ń ṣọ́ ààfin náà bá ya bò ó. Gẹ́gẹ́ bí ...

IG Rescinds Order on Essential Workers, Warns Against Undue Advantage

Image
Gani Salau The Inspector General of Police, Muhammad Adamu has rescinded his earlier order not to allow essential workers covering the COVID 19 activities to work freely during the lockdown. He however warned against abuse of the rules while on official duty. Adamu stated this in a press release made available to the press by the Police Public Relations Officer, Force Head Quarters, Abuja, ACP Frank MBA with reference  CZ.5300/FPRD/FHQ/ABJ/VOL2/ 20th May, 2020. "Meanwhile, the IGP enjoys all workers who fall within these categories not to take undue advantage of their positions and privileges to advance other purposes not connected with the performance of their duties within the stated period ".The IGP advised. While commenting on the enforcement of national curfew and inter state movement restriction orders placed by the Federal Government, Adamu stated that "it has become necessary to clear all ambiguity on the position of the Nigeria Police Force espec...

Ààrẹ Buhari dijú lé Ọ̀gá Àjọ NECO àti àwọn mẹ́rin mìíràn tó jàjẹbánu

Image
Fẹ́mi Akínṣọlá Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Muhammadu Buhari ti fi ọwọ́ òṣì júwe ilé fún adarí àjọ elétò ìdánwò àṣekágbá ti girama, NECO àti àwọn mẹ́rin mìíràn lórí ẹ̀sùn pé wọ́n ṣe màgòmágó. Nínú àtẹjáde tí Ààrẹ Buhari fi léde ló ti ní Ọjọ́gbọn Charles Uwakwe, Bamidele Olure, Shina Adetona, Tayo Odukoya àti Babatunde Aina ni wọ́n ti kọkọ fún ní ìwé lọ gbélé rẹ fún ìgbà díẹ̀ kí wọ́n fi ṣe ìwádìí fínífíní ẹ̀sùn ìwà àjẹbánu tí wọ́n fi kàn wọ́n. Wọ́n ní Uwakwe jẹ̀bi ẹ̀sùn lílo owó àjọ náà básubàsu gẹ́gẹ́ bí òfin àjọ náà ti ọdún 2007 sẹ tako ìwà àjẹbánu bẹ́ẹ̀. Ààrẹ wá késí i láti dá gbogbo ẹrù Ìjọba tó wà ní ọwọ́ rẹ̀ padà fún adelé darí àjọ náà tó wà níbẹ̀ lọ́wọ́lọ́wọ́. Bákan náà nínú àtẹjáde  ọ̀hún ni wọ́n sọ pé Arákùnrin Bamidele Olure tó jẹ́ adarí ẹ̀ka ìṣúná ní àjọ NECO ló jẹ̀bi ẹ̀sùn ṣíṣe owó àjọ náà tó wà ní ìkáwọ́ rẹ básubàsu, tí kò sì yẹ ní adarí ẹ̀ka náà mọ́. Ọ̀mọ̀wé Dókítà, Shina Adetona ni wọ́n fẹsun kàn ní tirẹ̀ pé ó ṣe jibiti, tó sì ṣe màgòmágó pẹ̀lú àkọsílẹ...

Eid-al-Fitr: FG Declares May 25, 26 Public Holidays

Image
The Federal Government has declared Monday 25 and Tuesday 26 May, 2020 as Public Holidays to mark this year’s Eid-al-Fitr Celebration. Director Press and Public Relations in the Ministry of Interior, Mohammed Manga disclosed this in a statement issued Thursday in Abuja on behalf of the Minister, Ogbeni Rauf Aregbesola. The statement noted that Aregbesola who made the declaration on behalf of the Federal Government congratulated all Muslim faithful for the successful completion of the Ramadan fast. “Aregbesola who called on them to replicate the life of kindness, love, tolerance, peace and good neighbourliness, as exemplified by the Holy Prophet Muhammad (Peace be upon Him), also expressed his concern about the spate of ethnic conflicts that has resurfaced in some parts of Northern Nigeria in recent times. “He advised Nigerians to see themselves as a single entity and thus learn to tolerate one another despite their ethnic and religious differences. “Ogbeni Aregbesola furt...

Leadership in difficult times: The BAF Example

Image
By Adl The popular axiom that "tough times never last, but tough people do," has best describes the challenges and difficulties many leaders are facing at this time.  In recent months, the novel coronavirus disease (COVID-19) has negatively impacted the business of governance all over the world and leaders are taking very tough decisions to manoeuvre the situation and prepare for the future. At some point, every business of government seems to have reached a rough patch, and while leaders must make tough decisions to improve the situation and save lives, they must as well pay close attention to improving the welfare of the people particularly the poor and the  vulnerable ones during this Covid-19 lockdown. In Nigeria and in particular, Ekiti State, this hasn't been an easy task. It can be hard to see the positive and good efforts of government when everything seems to be falling apart. But every government goes through rough patches and growing pains, and it...

Buhari Sacks NECO Registrar, Four Others

Image
Gani Salau    In what can be termed to  another surgical operation at the National Examination Council, NECO, President Muhammadu Buhari has approved the termination of the appointment of Prof. Charles Uwakwe as the Registrar/Chief Executive of the National Examinations Council. Uwakwe was accused of violating the Public Procurement Act (2007) and pursuant to PSR 03402 and part 1,schedule 4(1) of NECO. Buhari alongside approved the dismissal of Four Management Staff  from Service for various offences.They are, Mr Bamidele Olure, Acting Director, (Finance and Accounts),Dr Shina Adetona, Head of procurement Division, Mr Tayo Odukoya, Deputy Director and Barrister Babatunde Aina, Head of Legal and Board mathers. The Permanent Secretary Federal Ministry of Education, Arc. Sonny Echono on May 11th,2020 signed on behalf of the Education Minister, Uwakwe was accused of violating the Public procurement Act The letter reads: “after due consideration of the...

Celebrating Rotimi Ojomoyela, A Man of Class, Intimidating Stature

Image
BY Idowu Ariwodola To God alone be all the glory! My (3 in One), Rotimi Ojomoyela, is plus ONE today. My friend, brother and colleague, who i jocularly call 'aburo', simply because he relunctantly agreed that I took some couple of months from him! Dear good brother, i cannot but celebrate you because you are a full of life, a dogged fighter, an inocolistic revolutionary, resilient, courageous, dependable, consistent and loyal to a fault. Those who know, will always know. You were not born for your family, not even for your Town or State. You were deliberately born for humanity and selfless service across the land. And, that accounts for why I always tell you at every given opportunity, that you are still advancing more, to the very top. Without mincing words, Rotimi is unarguably, a pride of the family and journalism professoin. Stoutly and hugely built, he ordinarily commands respect on first sight. He is astoundly fashionable and combines talent with handsomeness a...